Yorùbá Bibeli

Eks 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

GBOGBO ijọ awọn ọmọ Israeli si rìn lati ijù Sini lọ, ni ìrin wọn, gẹgẹ bi ofin OLUWA, nwọn si dó ni Refidimu: omi kò si si fun awọn enia na lati mu.

Eks 17

Eks 17:1-4