Yorùbá Bibeli

Ẹk. Jer 1:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sioni nà ọwọ rẹ̀ jade, kò si sí ẹnikan lati tù u ninu: Oluwa ti paṣẹ niti Jakobu pe, ki awọn aninilara rẹ̀ ki o yi i kakiri: Jerusalemu dabi obinrin ẹlẹgbin lãrin wọn.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:11-21