Yorùbá Bibeli

Ẹk. Jer 1:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi nsọkun nitori nkan wọnyi; oju mi! oju mi ṣàn omi silẹ, nitoripe olutunu ati ẹniti iba mu ọkàn mi sọji jina si mi: awọn ọmọ mi run, nitoripe ọta bori.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:9-19