Yorùbá Bibeli

A. Oni 11:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA, Ọlọrun Israeli, si fi Sihoni, ati gbogbo enia rẹ̀ lé Israeli lọwọ, nwọn si kọlù wọn: Israeli si gbà gbogbo ilẹ awọn Amori, awọn enia ilẹ na.

A. Oni 11

A. Oni 11:16-31