Yorùbá Bibeli

A. Oni 11:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Sihoni kò gbẹkẹle Israeli lati kọja li àgbegbe rẹ̀: ṣugbọn Sihoni kó gbogbo enia rẹ̀ jọ, nwọn si dó ni Jahasi, nwọn si bá Israeli jagun.

A. Oni 11

A. Oni 11:12-28