Yorùbá Bibeli

Tit 2:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o máṣe irẹjẹ, ṣugbọn ki nwọn ki o mã fi iwa otitọ rere gbogbo han; ki nwọn ki o le mã ṣe ẹkọ́ Ọlọrun Olugbala wa li ọṣọ́ ninu ohun gbogbo.

Tit 2

Tit 2:3-15