Yorùbá Bibeli

Rut 4:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibatan na si wipe, Emi kò le rà a silẹ fun ara mi, ki emi má ba bà ilẹ-iní mi jẹ́: iwọ rà eyiti emi iba rà silẹ; nitori emi kò le rà a.

Rut 4

Rut 4:1-16