Yorùbá Bibeli

Rut 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Iwọ tani? On si dahùn wipe, Emi Rutu ọmọbinrin ọdọ rẹ ni: nitorina nà eti-aṣọ rẹ bò ọmọbinrin ọdọ rẹ; nitori iwọ ni ibatan ti o sunmọ wa.

Rut 3

Rut 3:6-13