Yorùbá Bibeli

Rut 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Boasi si jẹ ti o si mu tán, ti inu rẹ̀ si dùn, o lọ dubulẹ ni ikangun ikójọ ọkà: on si wá jẹjẹ, o si ṣí aṣọ ẹsẹ̀ rẹ̀, o si dubulẹ.

Rut 3

Rut 3:1-13