Yorùbá Bibeli

Rut 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li on wipe, Joko jẹ, ọmọbinrin mi, titi iwọ o fi mọ̀ bi ọ̀ran na yio ti jasi: nitoripe ọkunrin na ki yio simi, titi yio fi pari ọ̀ran na li oni.

Rut 3

Rut 3:16-18