Yorùbá Bibeli

Rut 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, ọmọbinrin mi máṣe bẹ̀ru; gbogbo eyiti iwọ wi li emi o ṣe fun ọ: nitori gbogbo agbajọ awọn enia mi li o mọ̀ pe obinrin rere ni iwọ iṣe.

Rut 3

Rut 3:1-17