Yorùbá Bibeli

Rut 2:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si lọ, o si dé oko, o si peṣẹ́-ọkà lẹhin awọn olukore: o si wa jẹ pe apa oko ti o bọ si jẹ́ ti Boasi, ti iṣe ibatan Elimeleki.

Rut 2

Rut 2:1-8