Yorùbá Bibeli

Rut 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki OLUWA ki o san ẹsan iṣẹ rẹ, ẹsan kikún ni ki a san fun ọ lati ọwọ́ OLUWA Ọlọrun Israeli wá, labẹ apa-iyẹ́ ẹniti iwọ wá gbẹkẹle.

Rut 2

Rut 2:4-22