Yorùbá Bibeli

Rom 8:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o si nwá inu ọkàn wo, o mọ̀ ohun ti inu Ẹmí, nitoriti o mbẹbẹ fun awọn enia mimọ́ gẹgẹ bi ifẹ Ọlọrun.

Rom 8

Rom 8:19-37