Yorùbá Bibeli

Rom 5:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ofin bọ si inu rẹ̀, ki ẹ̀ṣẹ le di pupọ. Ṣugbọn nibiti ẹ̀ṣẹ di pupọ, ore-ọfẹ di pupọ rekọja,

Rom 5

Rom 5:12-21