Yorùbá Bibeli

Rom 5:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì isi ṣe bi nipa ẹnikan ti o ṣẹ̀, li ẹ̀bun na: nitori idajọ ti ipasẹ ẹnikan wá fun idalẹbi ṣugbọn ẹ̀bun ọfẹ ti inu ẹ̀ṣẹ pupọ wá fun idalare.

Rom 5

Rom 5:10-21