Yorùbá Bibeli

Rom 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ bi, nigbati awa wà li ọtá, a mu wa ba Ọlọrun làja nipa ikú Ọmọ rẹ̀, melomelo, nigbati a là wa ni ìja tan, li a o gbà wa là nipa ìye rẹ̀.

Rom 5

Rom 5:1-17