Yorùbá Bibeli

Rom 13:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn ijoye kì iṣe ẹ̀ru si iṣẹ rere, bikoṣe si iṣẹ buburu. Njẹ iwọ ha fẹ ṣaibẹru aṣẹ wọn? ṣe eyi ti o dara, iwọ ó si gbà iyìn lati ọdọ rẹ̀:

Rom 13

Rom 13:1-5