Yorùbá Bibeli

Rom 12:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi ebi ba npa ọtá rẹ, fun u li onjẹ; bi ongbẹ ba ngbẹ ẹ, fun u li omi mu: ni ṣiṣe bẹ̃ iwọ ó kó ẹyín ina le e li ori.

Rom 12

Rom 12:18-21