Yorùbá Bibeli

Rom 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NITORINA mo fi iyọ́nu Ọlọrun bẹ̀ nyin, ará, ki ẹnyin ki o fi ara nyin fun Ọlọrun li ẹbọ ãye, mimọ́, itẹwọgbà, eyi ni iṣẹ-isìn nyin ti o tọ̀na.

Rom 12

Rom 12:1-2