Yorùbá Bibeli

Rom 11:34-36 Yorùbá Bibeli (YCE)

34. Nitori tali o mọ̀ inu Oluwa? tabi tani iṣe ìgbimọ rẹ̀?

35. Tabi tali o kọ́ fifun u, ti a o si san a pada fun u?

36. Nitori lati ọdọ rẹ̀, ati nipa rẹ̀, ati fun u li ohun gbogbo: ẹniti ogo wà fun lailai. Amin.