Yorùbá Bibeli

Rom 11:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bi a ti ke iwọ kuro lara igi oróro igbẹ́ nipa ẹda, ti a si lọ́ iwọ sinu igi oróro rere lodi si ti ẹda: melomelo li a o lọ́ awọn wọnyi, ti iṣe ẹka-iyẹka sara igi oróro wọn?

Rom 11

Rom 11:14-34