Yorùbá Bibeli

Rom 11:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi a ba yà ninu awọn ẹ̀ka kuro, ti a si lọ́ iwọ, ti iṣe igi oróro igbẹ́ sara wọn, ti iwọ si mba wọn pín ninu gbòngbo ati ọra igi oróro na;

Rom 11

Rom 11:12-19