Yorùbá Bibeli

O. Daf 92:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sa wò o, awọn ọta rẹ, Oluwa, sa wò o, awọn ọta rẹ yio ṣegbe; gbogbo oniṣẹ ẹ̀ṣẹ li a o tuka.

O. Daf 92

O. Daf 92:1-14