O. Daf 92:13-15 Yorùbá Bibeli (YCE) Awọn ẹniti a gbin ni ile Oluwa, yio gbà ni agbala Ọlọrun wa. Nwọn o ma so eso sibẹ ninu ogbó wọn: nwọn