Yorùbá Bibeli

O. Daf 84:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori pe ọjọ kan ninu agbala rẹ sanju ẹgbẹrun ọjọ lọ. Mo fẹ ki nkuku ma ṣe adena ni ile Ọlọrun mi, jù lati ma gbe agọ ìwa-buburu.

O. Daf 84

O. Daf 84:5-12