Yorùbá Bibeli

O. Daf 72:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ikúnwọ ọkà ni yio ma wà lori ilẹ, lori awọn òke nla li eso rẹ̀ yio ma mì bi Lebanoni: ati awọn ti inu ilu yio si ma gbà bi koriko ilẹ.

O. Daf 72

O. Daf 72:6-20