Yorùbá Bibeli

O. Daf 62:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiki ìro wọn ni lati já a tilẹ kuro ninu ọlá rẹ̀: nwọn nṣe inu didùn ninu eke: nwọn nfi ẹnu wọn sure, ṣugbọn nwọn ngegun ni inu wọn.

O. Daf 62

O. Daf 62:1-5