Yorùbá Bibeli

O. Daf 59:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn emi o kọrin agbara rẹ; nitõtọ, emi o kọrin ãnu rẹ kikan li owurọ: nitori pe iwọ li o ti nṣe àbo ati ibi-asala mi li ọjọ ipọnju mi.

O. Daf 59

O. Daf 59:7-17