Yorùbá Bibeli

O. Daf 57:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ṢÃNU fun mi: Ọlọrun, ṣãnu fun mi: nitoriti ọkàn mi gbẹkẹle ọ: lõtọ, li ojiji iyẹ-apa rẹ li emi o fi ṣe àbo mi, titi wahala wọnyi yio fi rekọja.

O. Daf 57

O. Daf 57:1-11