Yorùbá Bibeli

O. Daf 5:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi o ṣe ti emi, emi o wá sinu ile rẹ li ọ̀pọlọpọ ãnu rẹ: ninu ẹ̀ru rẹ li emi o tẹriba si iha tempili mimọ́ rẹ.

O. Daf 5

O. Daf 5:1-12