Yorùbá Bibeli

O. Daf 49:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe, igbati o ba kú, kì yio kó ohun kan lọ: ogo rẹ̀ kì yio sọkalẹ tọ̀ ọ lẹhin lọ.

O. Daf 49

O. Daf 49:13-20