Yorùbá Bibeli

O. Daf 39:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, gbọ́ adura mi, ki o si fi eti si ẹkún mi, ki o máṣe pa ẹnu rẹ mọ́ si omije mi: nitori alejo li emi lọdọ rẹ, ati atipo, bi gbogbo awọn baba mi ti ri.

O. Daf 39

O. Daf 39:4-13