Yorùbá Bibeli

O. Daf 37:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ simi ninu Oluwa, ki o si fi sũru duro dè e; máṣe ikanra nitori ẹniti o nri rere li ọ̀na rẹ̀, nitori ọkunrin na ti o nmu èro buburu ṣẹ.

O. Daf 37

O. Daf 37:5-15