Yorùbá Bibeli

O. Daf 37:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia buburu ti fà idà yọ, nwọn si ti fà ọrun wọn le, lati sọ talaka ati alaini kalẹ, ati lati pa iru awọn ti nrin li ọ̀na titọ.

O. Daf 37

O. Daf 37:7-18