Yorùbá Bibeli

O. Daf 19:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki ọ̀rọ ẹnu mi, ati iṣaro ọkàn mi, ki o ṣe itẹwọgba li oju rẹ, Oluwa, agbara mi, ati oludande mi.

O. Daf 19

O. Daf 19:6-14