Yorùbá Bibeli

O. Daf 18:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu ìṣẹ́ mi emi kepè Oluwa, emi si sọkun pe Ọlọrun mi: o gbohùn mi lati inu tempili rẹ̀ wá, ẹkún mi si wá si iwaju rẹ̀, ani si eti rẹ̀.

O. Daf 18

O. Daf 18:1-14