Yorùbá Bibeli

O. Daf 131:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA, aiya mi kò gbega, bẹ̃li oju mi kò gbé soke: bẹ̃li emi kò fi ọwọ mi le ọ̀ran nla, tabi le ohun ti o ga jù mi lọ.

O. Daf 131

O. Daf 131:1-3