Yorùbá Bibeli

O. Daf 129:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IGBA pupọ̀ ni nwọn ti npọ́n mi loju lati igba-ewe mi wá, ni ki Israeli ki o wi nisisiyi.

2. Igba pupọ̀ ni nwọn ti npọ́n mi loju lati igba-ewe mi wá: sibẹ nwọn kò ti ibori mi.

3. Awọn awalẹ̀ walẹ si ẹhin mi: nwọn si la aporo wọn gigun.