Yorùbá Bibeli

O. Daf 118:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olubukún li ẹniti o mbọ̀ wá li orukọ Oluwa: awa ti fi ibukún fun ọ lati ile Oluwa wá.

O. Daf 118

O. Daf 118:22-27