Yorùbá Bibeli

Neh 9:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti nwọn kò sin ọ ninu ijọba wọn, ati ninu ore rẹ nla ti iwọ fi fun wọn, ati ninu ilẹ nla ati ọlọra ti o fi si iwaju wọn, bẹ̃ni nwọn kò pada kuro ninu iṣẹ buburu wọn.

Neh 9

Neh 9:27-38