Yorùbá Bibeli

Neh 9:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ si fi ọwọ̀n awọ-sanma ṣe amọ̀na wọn li ọsan, ati li oru, ọwọ̀n iná, lati fun wọn ni imọlẹ li ọ̀na ninu eyiti nwọn o rin.

Neh 9

Neh 9:5-22