Yorùbá Bibeli

Neh 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Esra si fi ibukun fun Oluwa Ọlọrun, ti o tobi. Gbogbo enia si dahun pe, Amin, Amin! pẹlu gbigbe ọwọ wọn soke: nwọn si tẹ̀ ori wọn ba, nwọn si sìn Oluwa ni idojubòlẹ̀.

Neh 8

Neh 8:1-14