Yorùbá Bibeli

Neh 8:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kà ninu rẹ̀ niwaju ita ti o wà niwaju ẹnu-bode omi lati owurọ titi di idaji ọjọ, niwaju awọn ọkunrin ati awọn obinrin, ati awọn ti o le ye; gbogbo enia si tẹtisilẹ si iwe ofin.

Neh 8

Neh 8:1-4