Yorùbá Bibeli

Neh 7:61 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn wọnyi li o si goke lati Telhariṣa, Kerubu, Addoni, ati Immeri wá: ṣugbọn nwọn kò le fi ile baba wọn hàn, tabi iran wọn, bi nwọn iṣe ti Israeli.

Neh 7

Neh 7:57-65