Yorùbá Bibeli

Neh 7:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun mi si fi si mi li ọkàn lati ko awọn ijòye jọ, ati awọn olori, ati awọn enia, ki a le kà wọn nipa idile wọn. Mo si ri iwe idile awọn ti o kọ́ goke wá, mo ri pe, a kọ ọ sinu rẹ̀.

Neh 7

Neh 7:1-9