Yorùbá Bibeli

Neh 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni mo yàn awọn enia si ibi ti o rẹlẹ lẹhin odi, ati si ibi gbangba, mo tilẹ yàn awọn enia gẹgẹ bi idile wọn, pẹlu idà wọn, ọ̀kọ wọn, ati ọrun wọn.

Neh 4

Neh 4:8-18