Yorùbá Bibeli

Neh 13:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ni gbogbo àkoko yi, emi kò si ni Jerusalemu: nitori li ọdun kejilelọgbọn ti Artasasta ọba Babiloni, mo wá si ọdọ ọba, ati li opin ọjọ wọnni, mo gba àye lati ọdọ ọba.

Neh 13

Neh 13:1-14