Yorùbá Bibeli

Neh 13:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ha kọ́ awọn baba nyin ṣe, Ọlọrun kò ha mu ki gbogbo ibi yi wá sori wa, ati sori ilu yi? ṣugbọn ẹnyin mu ibinu ti o pọ̀ju wá sori Israeli nipa biba ọjọ isimi jẹ.

Neh 13

Neh 13:10-28