Yorùbá Bibeli

Neh 13:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ara Tire ngbe ibẹ pẹlu, ti nwọn mu ẹja, ati oniruru ohun èlo wá, nwọn si ntà li ọjọ isimi fun awọn ọmọ Juda, ati ni Jerusalemu.

Neh 13

Neh 13:12-19